Lefitiku 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ gbé adití ṣépè tabi kí ẹ gbé ohun ìdìgbòlù kalẹ̀ níwájú afọ́jú, ṣugbọn ẹ níláti bẹ̀rù Ọlọrun yín. Èmi ni OLUWA.

Lefitiku 19

Lefitiku 19:4-15