Lefitiku 19:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ kò gbọdọ̀ pọ́n aládùúgbò yín lójú tabi kí ẹ jà á lólè; owó iṣẹ́ tí alágbàṣe bá ba yín ṣe kò gbọdọ̀ di ọjọ́ keji lọ́wọ́ yín.

Lefitiku 19

Lefitiku 19:8-22