Lefitiku 16:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà yóo mú àwọn ewúrẹ́ mejeeji, yóo fà wọ́n kalẹ̀ níwájú OLUWA, ní ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ.

Lefitiku 16

Lefitiku 16:3-14