Lefitiku 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Aaroni yóo fi ọ̀dọ́ mààlúù kan rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ara rẹ̀, yóo sì ṣe ètùtù fún ara rẹ̀ ati ilé rẹ̀.

Lefitiku 16

Lefitiku 16:1-15