Lefitiku 11:29 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn tí wọ́n jẹ́ aláìmọ́ fun yín ninu gbogbo àwọn ohun tí ń rìn lórí ilẹ̀ ni: asín, ati èkúté, ati àwọn oríṣìíríṣìí aláǹgbá ńlá,

Lefitiku 11

Lefitiku 11:26-38