Lefitiku 11:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni bá gbé òkú wọn, kí ó fọ aṣọ rẹ̀, yóo sì jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́; ohun àìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fun yín.

Lefitiku 11

Lefitiku 11:24-36