Lefitiku 11:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA rán Mose ati Aaroni pé

2. kí wọ́n sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, “Àwọn ẹran tí wọ́n lè jẹ lára àwọn ẹran tí wọ́n wà láyé nìwọ̀nyí:

Lefitiku 11