Lefitiku 11:2 BIBELI MIMỌ (BM)

kí wọ́n sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, “Àwọn ẹran tí wọ́n lè jẹ lára àwọn ẹran tí wọ́n wà láyé nìwọ̀nyí:

Lefitiku 11

Lefitiku 11:1-5