Lefitiku 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó gé e sí wẹ́wẹ́, ati orí rẹ̀, ati ọ̀rá rẹ̀, kí alufaa to gbogbo rẹ̀ sórí igi tí ó wà ninu iná lórí pẹpẹ.

Lefitiku 1

Lefitiku 1:7-17