Lefitiku 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó pa á ní apá ìhà àríwá pẹpẹ níwájú OLUWA, kí àwọn ọmọ Aaroni, alufaa, da ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sí ara pẹpẹ náà yíká.

Lefitiku 1

Lefitiku 1:8-17