Kronika Kinni 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Usi ni ó bí Isiraya. Isiraya sì bí ọmọ mẹrin: Mikaeli, Ọbadaya, Joẹli, ati Iṣaya; wọ́n di marun-un, àwọn maraarun ni wọ́n sì jẹ́ ìjòyè.

Kronika Kinni 7

Kronika Kinni 7:1-7