Kronika Kinni 29:16 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, Ọlọrun wa, tìrẹ ni gbogbo ohun tí a mú wá, láti fi kọ́ ilé fún orúkọ mímọ́ rẹ, ọ̀dọ̀ rẹ ni wọ́n sì ti wá.

Kronika Kinni 29

Kronika Kinni 29:10-26