Kronika Kinni 29:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àjèjì ati àlejò ni a jẹ́ ní ojú rẹ, gẹ́gẹ́ bí àwọn baba ńlá wa. Gbogbo ọjọ́ wa láyé dàbí òjìji, kò lè wà pẹ́ títí.

Kronika Kinni 29

Kronika Kinni 29:10-19