Kronika Kinni 28:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“OLUWA sọ fún mi pé, ‘Solomoni, ọmọ rẹ ni yóo kọ́ ilé mi ati àgbàlá mi, nítorí mo ti yàn án láti jẹ́ ọmọ mi, èmi yóo sì jẹ́ baba fún un.

Kronika Kinni 28

Kronika Kinni 28:1-11