Kronika Kinni 28:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA fún mi ní ọmọ pupọ, ṣugbọn ninu gbogbo wọn, ó yan Solomoni láti jọba lórí ìtẹ́ ìjọba rẹ̀ lórí Israẹli.

Kronika Kinni 28

Kronika Kinni 28:1-6