Kronika Kinni 27:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹnaya yìí jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn ọgbọ̀n akọni jagunjagun, òun sì ni olórí wọn. Amisabadi ọmọ rẹ̀ ni ó ń ṣe àkóso ìpín rẹ̀.

Kronika Kinni 27

Kronika Kinni 27:1-15