Kronika Kinni 27:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Balogun kẹta, tí ó wà fún oṣù kẹta ni Bẹnaya, ọmọ Jehoiada, alufaa. Iye àwọn tí ó wà ninu ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaaji (24,000).

Kronika Kinni 27

Kronika Kinni 27:3-12