Kronika Kinni 26:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ladani, ọ̀kan ninu ìran Geriṣoni, ní àwọn ọmọkunrin tí wọ́n jẹ́ olórí ìdílé wọn, ọ̀kan ninu wọn ń jẹ́ Jehieli.

Kronika Kinni 26

Kronika Kinni 26:11-22