Kronika Kinni 26:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahija, láti inú ẹ̀yà Lefi, ni ó ń bojútó àwọn ibi ìṣúra tí ó wà ninu ilé OLUWA ati ibi tí wọn ń kó àwọn ẹ̀bùn tí a yà sọ́tọ̀ fún Ọlọrun sí.

Kronika Kinni 26

Kronika Kinni 26:13-28