Kronika Kinni 25:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ Hemani, aríran ọba, ni gbogbo wọn, gẹ́gẹ́ bí ìlérí tí Ọlọrun ṣe láti gbé Hemani ga; Ọlọrun fún un ní ọmọkunrin mẹrinla ati ọmọbinrin mẹta.

Kronika Kinni 25

Kronika Kinni 25:1-12