Kronika Kinni 25:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Hemani ni: Bukaya, Matanaya, Usieli, Ṣebueli, ati Jerimotu, Hananaya, Hanani, Eliata, Gidaliti, ati Romamiti Eseri, Joṣibekaṣa, Maloti, Hotiri, ati Mahasioti.

Kronika Kinni 25

Kronika Kinni 25:1-9