Kronika Kinni 25:30-31 BIBELI MIMỌ (BM) Ẹkẹtalelogun mú Mahasioti, òun ati àwọn ọmọkunrin rẹ̀, ati àwọn arakunrin rẹ̀ jẹ́ mejila.