Kronika Kinni 26:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí a ti ṣe pín iṣẹ́ fún àwọn aṣọ́nà nìwọ̀nyí: Meṣelemaya, ọmọ Kore, ní ìdílé Asafu, ninu ìran Kora.

Kronika Kinni 26

Kronika Kinni 26:1-3