Kronika Kinni 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Joabu ati àwọn ogun Israẹli súnmọ́ àwọn ọmọ ogun Siria láti bá wọn jà, ṣugbọn àwọn ọmọ ogun Siria sá fún wọn.

Kronika Kinni 19

Kronika Kinni 19:9-19