Kronika Kinni 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó ọpọlọpọ idẹ ní Tibihati ati Kuni, tí wọ́n wà lábẹ́ Hadadeseri. Idẹ yìí ni Solomoni fi ṣe agbada omi ńlá ati òpó ati àwọn ohun èlò idẹ fún ilé OLUWA.

Kronika Kinni 18

Kronika Kinni 18:3-10