Kronika Kinni 18:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi gba àwọn apata wúrà tí wọ́n wà lọ́wọ́ àwọn iranṣẹ Hadadeseri, ó kó wọn lọ sí Jerusalẹmu.

Kronika Kinni 18

Kronika Kinni 18:6-12