Kronika Kinni 12:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣimaya, ará Gibeoni, akikanju jagunjagun ati ọ̀kan ninu “àwọn ọgbọ̀n” jagunjagun olókìkí ni, òun sì ni olórí wọn; Jeremaya, Jahasieli, Johanani ati Josabadi ará Gedera.

Kronika Kinni 12

Kronika Kinni 12:1-7