Kronika Kinni 12:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Olórí wọn ni Ahieseri, lẹ́yìn náà, Joaṣi, ọmọ Ṣemaa; ará Gibea ni àwọn mejeeji. Lẹ́yìn wọn ni: Jesieli ati Peleti, àwọn ọmọ Asimafeti; Beraka, ati Jehu, ará Anatoti.

Kronika Kinni 12

Kronika Kinni 12:1-5