Kronika Kinni 11:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn òun ati àwọn eniyan rẹ̀ dúró gbọningbọnin ninu oko náà, wọ́n bá àwọn ará Filistia jà. OLUWA gbà wọ́n, ó sì fún wọn ní ìṣẹ́gun ńlá.

Kronika Kinni 11

Kronika Kinni 11:9-24