Kronika Kinni 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wà pẹlu Dafidi nígbà tí Dafidi bá àwọn ará Filistia jagun ní Pasi Damimu, wọ́n wà ninu oko ọkà baali kan nígbà tí àwọn ọmọ ogun Israẹli bẹ̀rẹ̀ sí sá fún àwọn ará Filistia.

Kronika Kinni 11

Kronika Kinni 11:3-23