Kronika Keji 8:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Solomoni ṣe ṣe gbogbo iṣẹ́ tí ó ṣe láti ìgbà tí ó ti fi ìpìlẹ̀ ilé OLUWA lélẹ̀ títí di ìgbà tí ó parí iṣẹ́ náà patapata.

Kronika Keji 8

Kronika Keji 8:13-18