Kronika Keji 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò sì yapa kúrò ninu ìlànà tí Dafidi fi lélẹ̀ fún àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi nípa àwọn ohun tí wọ́n gbọdọ̀ máa ṣe, ati nípa ilé ìṣúra.

Kronika Keji 8

Kronika Keji 8:10-18