Kronika Keji 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

n óo fi ìdí ìjọba rẹ múlẹ̀, bí mo ti bá Dafidi, baba rẹ, dá majẹmu pé, ìran rẹ̀ ni yóo máa jọba lórí Israẹli.

Kronika Keji 7

Kronika Keji 7:16-22