Kronika Keji 7:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn, bí ìwọ bá tẹ̀lé ìlànà mi gẹ́gẹ́ bí Dafidi baba rẹ ti ṣe, tí o pa gbogbo òfin mi mọ́, tí o tẹ̀lé ìlànà ati àṣẹ mi,

Kronika Keji 7

Kronika Keji 7:16-22