Kronika Keji 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni Solomoni ṣe parí ilé OLUWA ati ààfin rẹ̀. Gbogbo ohun tí ó ní lọ́kàn láti ṣe sí ilé OLUWA ati sí ilé ti ara rẹ̀, ni ó ṣe ní àṣeyọrí.

Kronika Keji 7

Kronika Keji 7:2-18