Kronika Keji 7:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹtalelogun oṣù keje, Solomoni ní kí àwọn eniyan máa pada lọ sílé wọn. Inú wọn dùn nítorí ohun rere tí OLUWA ṣe fún Dafidi, ati Solomoni ati gbogbo Israẹli.

Kronika Keji 7

Kronika Keji 7:6-12