Kronika Keji 36:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni Jehoiakimu nígbà tí ó jọba. Ó wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanla. Ohun tí ó ṣe burú lójú OLUWA Ọlọrun rẹ̀.

Kronika Keji 36

Kronika Keji 36:1-15