Kronika Keji 36:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Neko, ọba Ijipti fi Eliakimu, arakunrin Joahasi jọba lórí Jerusalẹmu ati Juda, ó yí orúkọ rẹ̀ pada sí Jehoiakimu, ó sì mú Joahasi lọ sí Ijipti.

Kronika Keji 36

Kronika Keji 36:1-9