Kronika Keji 35:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kó ara yín jọ ní ìdílé ìdílé ati ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́ gẹ́gẹ́ bí ìlànà Dafidi, ọba Israẹli ati ti Solomoni ọmọ rẹ̀.

Kronika Keji 35

Kronika Keji 35:2-13