Kronika Keji 35:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó yan àwọn alufaa sí ipò wọn, ó sì gbà wọ́n níyànjú kí wọ́n ṣe iṣẹ́ wọn ninu ilé OLUWA.

Kronika Keji 35

Kronika Keji 35:1-5