Kronika Keji 35:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Josaya ṣe Àjọ Ìrékọjá fún OLUWA ní Jerusalẹmu. Ní ọjọ́ kẹrinla, oṣù kinni ni wọ́n pa ọ̀dọ́ aguntan Àjọ Ìrékọjá.

Kronika Keji 35

Kronika Keji 35:1-2