Kronika Keji 34:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Hilikaya sọ fún Ṣafani akọ̀wé, ó ní, “Mo rí ìwé òfin ninu ilé OLUWA.” Ó fún Ṣafani ní ìwé náà,

Kronika Keji 34

Kronika Keji 34:11-18