Kronika Keji 34:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọn ń kó owó tí àwọn eniyan ti mú wá sinu ilé OLUWA jáde, Hilikaya, alufaa rí ìwé òfin OLUWA tí Ọlọrun fún Mose.

Kronika Keji 34

Kronika Keji 34:13-21