Kronika Keji 34:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sanwó fún àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà ati àwọn tí wọn ń mọlé, láti ra òkúta gbígbẹ́ ati pákó ati igi, kí wọ́n fi tún àwọn ilé tí àwọn ọba Juda ti sọ di àlàpà kọ́.

Kronika Keji 34

Kronika Keji 34:4-16