Kronika Keji 34:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kó owó náà fún àwọn tí ń ṣe àbojútó iṣẹ́ náà. Àwọn ni wọ́n ń sanwó fún àwọn tí wọn ń tún ilé OLUWA ṣe.

Kronika Keji 34

Kronika Keji 34:1-16