Kronika Keji 33:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gbadura sí OLUWA, OLUWA gbọ́ adura rẹ̀, ó sì mú un pada wá sórí ìtẹ́ rẹ̀ ní Jerusalẹmu. Ó wá mọ̀ nígbà náà pé OLUWA ni Ọlọrun.

Kronika Keji 33

Kronika Keji 33:5-18