Kronika Keji 33:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó wà ninu ìpọ́njú ó wá ojurere OLUWA Ọlọrun, ó sì rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ patapata níwájú Ọlọrun àwọn baba rẹ̀.

Kronika Keji 33

Kronika Keji 33:9-21