Kronika Keji 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gbé àwọn òpó náà kalẹ̀ níwájú tẹmpili, ọ̀kan ní ìhà àríwá, wọ́n ń pè é ní Jakini, ekeji ní ìhà gúsù, wọ́n ń pè é ní Boasi.

Kronika Keji 3

Kronika Keji 3:11-17