Kronika Keji 3:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe àwọn nǹkankan bí ẹ̀wọ̀n, ó fi wọ́n sórí àwọn òpó náà. Ó sì ṣe ọgọrun-un (100) èso pomegiranate, ó so wọ́n mọ́ àwọn ẹ̀wọ̀n náà.

Kronika Keji 3

Kronika Keji 3:15-17