Kronika Keji 29:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya ọba dìde ní òwúrọ̀ kutukutu, ó kó gbogbo àwọn ìjòyè ìlú jọ, wọ́n bá lọ sinu ilé OLUWA.

Kronika Keji 29

Kronika Keji 29:10-24